Diutaronomi 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ranti pé ẹ ti jẹ́ ẹrú rí ní ilẹ̀ Ijipti. Ẹ ṣọ́ra kí ẹ lè máa tẹ̀lé àwọn ìlànà wọnyi.

Diutaronomi 16

Diutaronomi 16:11-14