Diutaronomi 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn kò ní sí ẹnikẹ́ni ninu yín tí yóo jẹ́ talaka, nítorí pé, OLUWA Ọlọrun yín yóo bukun yín, ní ilẹ̀ tí ó fun yín láti gbà,

Diutaronomi 15

Diutaronomi 15:1-7