Diutaronomi 15:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn tí ó bá wí fun yín pé, òun kò ní jáde ninu ilé yín, nítorí pé ó fẹ́ràn ẹ̀yin ati gbogbo ìdílé yín, nítorí pé ó dára fún un nígbà tí ó wà lọ́dọ̀ yín,

Diutaronomi 15

Diutaronomi 15:9-23