Diutaronomi 14:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ gbàgbé àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n wà láàrin yín nítorí pé, wọn kò ní ìpín tabi ohun ìní láàrin yín.

Diutaronomi 14

Diutaronomi 14:21-29