Diutaronomi 14:25 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ tà á, kí ẹ sì gba owó rẹ̀ sọ́wọ́, kí ẹ kó owó náà lọ sí ibi tí OLUWA Ọlọrun yín bá yàn pé kí ẹ ti máa sin òun.

Diutaronomi 14

Diutaronomi 14:15-27