Diutaronomi 13:8 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò gbọdọ̀ gbọ́ tirẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni o kò gbọdọ̀ dá a lóhùn. O kò gbọdọ̀ ṣàánú fún un, o kò sì gbọdọ̀ bò ó.

Diutaronomi 13

Diutaronomi 13:7-16