Diutaronomi 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

tí gbogbo nǹkan tí ó ń sọ sì ń rí bẹ́ẹ̀; bí ó bá wí pé kí ẹ wá lọ bọ oriṣa mìíràn tí ẹ kò mọ̀ rí,

Diutaronomi 13

Diutaronomi 13:1-3