Diutaronomi 13:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa gbọ́ ti OLUWA Ọlọrun yín, kí ẹ sì máa pa gbogbo òfin rẹ̀, tí mo fun yín lónìí mọ́, kí ẹ sì máa ṣe ohun tí ó tọ́ lójú OLUWA Ọlọrun yín.

Diutaronomi 13

Diutaronomi 13:17-18