Diutaronomi 13:15 BIBELI MIMỌ (BM)

idà ni kí ẹ fi pa àwọn tí wọn ń gbé ìlú náà. Ẹ pa wọ́n run patapata, ati gbogbo ohun tí ó wà níbẹ̀; ẹ fi idà pa gbogbo wọn ati àwọn ẹran ọ̀sìn wọn.

Diutaronomi 13

Diutaronomi 13:10-16