Diutaronomi 12:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ẹ kò tíì dé ibi ìsinmi ati ilẹ̀ ìní tí OLUWA Ọlọrun yín yóo fun yín.

Diutaronomi 12

Diutaronomi 12:1-10