Diutaronomi 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ibi tí OLUWA bá yàn láti gbé ibùjókòó rẹ̀ kà láàrin gbogbo àwọn ẹ̀yà, ibẹ̀ ni kí ẹ máa lọ.

Diutaronomi 12

Diutaronomi 12:2-14