Diutaronomi 12:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati ẹni tí ó mọ́ ati ẹni tí kò mọ́ ni ó lè jẹ ninu ẹran náà bí ìgbà tí eniyan ń jẹ ẹran ẹtu tabi ti àgbọ̀nrín.

Diutaronomi 12

Diutaronomi 12:12-29