Diutaronomi 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn ìlànà ati òfin, tí ẹ óo máa tẹ̀lé lẹ́sẹẹsẹ, ní gbogbo ọjọ́ ayé yín ní ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun àwọn baba yín ti fi fun yín láti gbà, nìyí:

Diutaronomi 12

Diutaronomi 12:1-11