Diutaronomi 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ gbọdọ̀ pa gbogbo òfin tí mo fun yín lónìí mọ́ kí ẹ lè ní agbára tó láti gba ilẹ̀ tí ẹ̀ ń rékọjá lọ láti gbà.

Diutaronomi 11

Diutaronomi 11:2-18