Diutaronomi 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ṣọ́ra, kí ẹ̀tàn má baà wọ inú ọkàn yín, kí ẹ má baà yipada sí àwọn oriṣa, kí ẹ sì máa bọ wọ́n.

Diutaronomi 11

Diutaronomi 11:9-22