Diutaronomi 11:14 BIBELI MIMỌ (BM)

yóo rọ òjò sórí ilẹ̀ yín ní àkókò rẹ̀, ati òjò àkọ́rọ̀ ati ti àrọ̀kẹ́yìn, kí ẹ baà lè kórè ọkà, ọtí waini, ati òróró olifi yín.

Diutaronomi 11

Diutaronomi 11:10-19