Diutaronomi 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ fẹ́ràn OLUWA Ọlọrun yín, kí ẹ sì máa tẹ̀lé gbogbo ìkìlọ̀ ati ìlànà, ati ìdájọ́, ati òfin rẹ̀ nígbà gbogbo.

Diutaronomi 11

Diutaronomi 11:1-8