Diutaronomi 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ni àwọn ẹ̀yà Lefi kò fi ní ìpín tabi ogún pẹlu àwọn arakunrin wọn. OLUWA ni ìpín wọn gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun yín ti wí fún wọn.)

Diutaronomi 10

Diutaronomi 10:6-10