Diutaronomi 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbéra láti ibẹ̀, wọ́n lọ sí Gudigoda. Láti Gudigoda, wọ́n lọ sí Jotibata, ilẹ̀ tí ó kún fún ọpọlọpọ odò tí ń ṣàn.

Diutaronomi 10

Diutaronomi 10:5-15