Diutaronomi 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ gbọ́ràn sí Ọlọrun lẹ́nu, kí ẹ má sì ṣe oríkunkun mọ́.

Diutaronomi 10

Diutaronomi 10:9-21