Diutaronomi 10:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún mi pé, ‘Gbéra, kí o máa lọ láti ṣáájú àwọn eniyan náà, kí wọ́n lè lọ gba ilẹ̀ tí mo búra fún wọn pé n óo fún wọn.’

Diutaronomi 10

Diutaronomi 10:1-20