Diutaronomi 1:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní tiyín, ó ní kí ẹ yipada, kí ẹ sì máa lọ sinu aṣálẹ̀, ní apá ọ̀nà Òkun Pupa.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:32-42