Diutaronomi 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

lẹ́yìn tí ó ti ṣẹgun Sihoni, ọba àwọn ará Amori tí ń gbé Heṣiboni; ati Ogu, ọba àwọn ará Baṣani, tí ń gbé Aṣitarotu ati Edirei.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:2-14