Diutaronomi 1:30 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun yín tí ń ṣáájú yín ni yóo jà fun yín, gẹ́gẹ́ bí ó ti jà fun yín ní ilẹ̀ Ijipti, tí ẹ̀yin náà sì fi ojú ara yín rí i.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:20-38