Diutaronomi 1:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“Sibẹsibẹ, ẹ kọ̀, ẹ kò lọ, ẹ ṣe orí kunkun sí àṣẹ tí OLUWA Ọlọrun yín pa fun yín.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:16-30