Diutaronomi 1:23 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọ̀rọ̀ yín dára lójú mi, mo sì yan ọkunrin mejila láàrin yín, ọkunrin kọ̀ọ̀kan láàrin ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:20-26