Diutaronomi 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí OLUWA Ọlọrun àwọn baba ńlá yín jẹ́ kí ẹ tún pọ̀ jù báyìí lọ lọ́nà ẹgbẹrun. Kí ó sì bukun yín gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí fun yín.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:6-19