Daniẹli 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ti ń gbadura, ni Geburẹli, tí mo rí lójúran ní àkọ́kọ́ bá yára fò wá sọ́dọ̀ mi, ní àkókò ẹbọ àṣáálẹ́.

Daniẹli 9

Daniẹli 9:11-27