Daniẹli 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

A kò gbọ́ tìrẹ OLUWA Ọlọrun wa, bẹ́ẹ̀ ni a kò pa òfin rẹ tí o fi rán àwọn wolii, iranṣẹ rẹ sí wa mọ́.

Daniẹli 9

Daniẹli 9:3-14