Daniẹli 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ti gbé ojú sókè, mo rí i tí àgbò kan dúró létí odò, ó ní ìwo meji tí ó ga sókè, ṣugbọn ọ̀kan gùn ju ekeji lọ. Èyí tí ó gùn jù ni ó hù kẹ́yìn.

Daniẹli 8

Daniẹli 8:1-12