Daniẹli 8:23 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ìjọba wọn bá ń lọ sópin, tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn bá kún ojú ìwọ̀n, ọba kan tí ojú rẹ̀ le, tí ó ní àrékérekè, tí ó sì lágbára yóo gorí oyè.

Daniẹli 8

Daniẹli 8:19-25