Daniẹli 8:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjọba Giriki ni òbúkọ onírun jákujàku tí o rí. Ọba àkọ́kọ́ tí yóo jẹ níbẹ̀ ni ìwo ńlá tí ó wà láàrin ojú rẹ̀.

Daniẹli 8

Daniẹli 8:19-27