Daniẹli 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí mo ti ń wò mo tún rí ẹranko mìíràn tí ó dàbí ẹkùn, òun náà ní ìyẹ́ mẹrin lẹ́yìn. Ó ní orí mẹrin. A sì fún un ní agbára láti jọba.

Daniẹli 7

Daniẹli 7:5-8