Daniẹli 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo wò yíká nítorí ọ̀rọ̀ ńláńlá tí ìwo kékeré yìí ń fi ẹnu sọ, mo sì rí i tí wọ́n pa ẹranko náà, tí wọ́n sì jó òkú rẹ̀ níná.

Daniẹli 7

Daniẹli 7:6-20