Daniẹli 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ fún ara wọn pé, “A kò ní rí ẹ̀sùn kà sí Daniẹli lẹ́sẹ̀, àfi ohun tí ó bá jẹmọ́ òfin Ọlọrun rẹ̀.”

Daniẹli 6

Daniẹli 6:1-10