Daniẹli 6:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń gbani là,ó ń dáni nídè.Ó ń ṣiṣẹ́ àánú tí ó yani lẹ́nu ní ọ̀run ati ní ayé.Òun ni ó gba Daniẹli lọ́wọ́ agbára kinniun.”

Daniẹli 6

Daniẹli 6:26-27