Daniẹli 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó yan àwọn mẹta láti máa ṣe àbojútó gbogbo wọn, Daniẹli sì jẹ́ ọ̀kan ninu wọn. Àwọn mẹta wọnyi ni àwọn ọgọfa (120) gomina náà yóo máa jábọ̀ fún.

Daniẹli 6

Daniẹli 6:1-4