Daniẹli 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọba gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ọkàn rẹ̀ dàrú lọpọlọpọ, ó sa gbogbo ipá rẹ̀ títí ilẹ̀ fi ṣú láti gba Daniẹli sílẹ̀.

Daniẹli 6

Daniẹli 6:6-22