Daniẹli 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin wọnyi bá kó ara wọn jọ. Wọ́n wá wo Daniẹli níbi tí ó ti ń gbadura, tí ó sì ń bẹ̀bẹ̀ níwájú Ọlọrun rẹ̀.

Daniẹli 6

Daniẹli 6:10-12