Daniẹli 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn Beṣasari dàrú, ojú rẹ̀ yipada. Àwọn ìjòyè rẹ̀ dààmú, wọn kò sì mọ ohun tí wọ́n lè ṣe.

Daniẹli 5

Daniẹli 5:8-11