Daniẹli 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn gbogbo wọn patapata ni Daniẹli dé, tí a sọ ní Beteṣasari, orúkọ oriṣa mi, Daniẹli yìí ní ẹ̀mí Ọlọrun ninu. Mo rọ́ àlá mi fún un, mo ní:

Daniẹli 4

Daniẹli 4:7-18