Daniẹli 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo lá àlá kan tí ó bà mí lẹ́rù. Èrò ọkàn mi ati ìran tí mo rí lórí ibùsùn mi kó ìdààmú bá mi.

Daniẹli 4

Daniẹli 4:1-15