Daniẹli 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Iṣẹ́ rẹ̀ tóbi gan-an!Iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ sì lágbára lọpọlọpọ!Títí ayérayé ni ìjọba rẹ̀,àtìrandíran rẹ̀ ni yóo sì máa jọba.

Daniẹli 4

Daniẹli 4:2-13