Daniẹli 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọba ni igi yìí, ìwọ ni o dàgbà, tí o di igi ńlá, tí o sì lágbára. Òkìkí rẹ kàn dé ọ̀run, ìjọba rẹ sì kárí gbogbo ayé.

Daniẹli 4

Daniẹli 4:19-27