Daniẹli 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Igi tí o rí, tí ó dàgbà, tí ó lágbára, tí orí rẹ̀ sì kan ọ̀run dé ibi pé gbogbo eniyan lè rí i,

Daniẹli 4

Daniẹli 4:10-27