Daniẹli 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

pé nígbà tí ẹ bá gbọ́ ìró fèrè, dùùrù, ìlù, hapu, ati oniruuru orin, kí ẹ dojúbolẹ̀ kí ẹ sin ère wúrà tí ọba Nebukadinesari gbé kalẹ̀.

Daniẹli 3

Daniẹli 3:1-13