Daniẹli 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún pàṣẹ pé kí àwọn akọni ninu àwọn ọmọ ogun rẹ̀ di Ṣadiraki, Meṣaki ati Abedinego, kí wọ́n sì sọ wọ́n sinu adágún iná.

Daniẹli 3

Daniẹli 3:19-22