Daniẹli 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dá wọn lóhùn pé, “Mo mọ̀ dájú pé ẹ kàn fẹ́ máa fi ọgbọ́n fi àkókò ṣòfò ni, nítorí ẹ ti mọ̀ pé bí mo ti wí ni n óo ṣe.

Daniẹli 2

Daniẹli 2:3-14