Daniẹli 2:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá wólẹ̀ níwájú Daniẹli, ó fi orí balẹ̀ fún un, ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n rúbọ kí wọ́n sì sun turari sí Daniẹli.

Daniẹli 2

Daniẹli 2:45-48