Daniẹli 2:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o ti ń wò ó, òkúta kan là, ó sì ré bọ́ láti òkè, ó bá ère náà ní ẹsẹ̀ mejeeji tí ó jẹ́ àdàlú irin ati amọ̀, mejeeji sì fọ́ túútúú.

Daniẹli 2

Daniẹli 2:26-38